← Àwon ètò
Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Luk 20
Ìhìnrere Luku
24 Awọn ọjọ
Luku ṣe àkọsílẹ̀ ẹ̀kún àlàyé bí ẹlẹ́rìí nípa ìgbé-ayé, ikú àti àjínde Jesu. Ètò ẹsẹ̀-Bibeli-kan-lójúmọ́ yìí pèsè àkọsílẹ̀ lẹ́sẹẹsẹ tó dájú nípa àwọn ìṣẹ̀lẹ̀, ó sì tún mú wa mọ Olùgbàlà ológo náà. Òun wá láti wá àwọn tó sọnù láti gbà wọ́n là, Ó sì pè wá sínú iṣẹ́ àánú tí a rán-an wá fún náà. YouVersion ni ó ṣàgbékalẹ̀ ètò yìí.