← Àwon ètò
Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Mat 13:7
![Ṣé Mo Lè B'orí Ẹ̀ṣẹ̀ àtí Ìdánwò Nítòótọ́?](/_next/image?url=https%3A%2F%2F%2F%2Fimageproxy.youversionapistaging.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans-staging%2F20280%2F640x360.jpg&w=1920&q=75)
Ṣé Mo Lè B'orí Ẹ̀ṣẹ̀ àtí Ìdánwò Nítòótọ́?
Ọjọ marun
Ǹjẹ́ o ti bi ara rẹ léèrè rí pé, "Kílódé tí mo ṣì ńbá ẹ̀ṣẹ̀ yẹn já ìjàkadì?" Àpóstélì Pọ́ọ́lù pàápàá sọ bẹ́ẹ̀ ní Róòmù 7:15: "Kìí ṣe ohun tí mo fẹ́ ni èmi ńṣe, ṣùgbọ́n ohun tí mo kórìra ni èmi ńṣe." Báwo ni a ṣe lè dá ẹ̀ṣẹ̀ l'ọ́wọ́ kọ́ kí ó má baà p'agi dínà ìgbé-ayé ẹ̀mí wa? Ṣé èyí tilẹ̀ ṣeéṣe? Jẹ́ kí á jíròrò lórí ẹ̀ṣẹ̀, ìdanwò, Èṣù, àti, ìfẹ́ Ọlọ́run.
![Òwe Afunrugbin](/_next/image?url=https%3A%2F%2F%2F%2Fimageproxy.youversionapistaging.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans-staging%2F49855%2F640x360.jpg&w=1920&q=75)
Òwe Afunrugbin
7 Awọn ọjọ
Jésù sọ àkàwé kan nípa afúnrúgbìn kan tó jáde lọ fúnrúgbìn. Ọkà naa ṣubu lori oriṣiriṣi awọn ile ati pe o ni awọn esi oriṣiriṣi ti o da lori ile ti o ṣubu lori. Nínú ètò ìfọkànsìn ti ọ̀sẹ̀ yìí, a máa wo àwọn ilẹ̀ wọ̀nyí, ipa tí wọ́n ní lórí ọkà, àti bí wọ́n ṣe kan àwọn onígbàgbọ́ lónìí.