Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Mat 28:20

Sọrọ Pẹlu Ọlọrun Ni Adura
Ọjọ́ mẹ́rin
Igbesi aye ẹbi le jẹ ošišẹ, ati pe a le ma gba akoko lati gbadura-jẹ ki o nikan ranti lati ṣe iranlọwọ fun awọn ọmọ wa dagba iwa ti pẹlu Ọlọrun ni ọjọ wọn. Ninu eto yii, ẹbi rẹ yoo ri bi Elo Ọlọrun fẹ lati gbọ lati ọdọ wa ati bi adura ṣe le mu ibasepo wa pẹlu Rẹ ati ọkan wa. Kọọkan ọjọ kan pẹlu adura adura, imọran kika Iwe-ẹri ati alaye, iṣẹ-ṣiṣe, ati awọn ibeere ijiroro.

Ìgbésẹ̀ Mẹ́fà Lọsí Ìdarí Tó Dára jù
Ọjọ́ méje
Ǹjẹ́ o ṣe tán láti dàgbà si gẹ́gẹ́bí olùdarí? Craig Groeschel ṣe ìtúpalẹ̀ àwọn ìgbésẹ̀ mẹ́fà tí a fẹsẹ̀ rẹ̀ múlẹ̀ nínú Bíbélì èyí tí ẹnikẹ́ni le tẹ̀lé láti di olùdarí tó dára. Ṣàwárí ìséra-ẹni láti bẹ̀rẹ̀, ìgboyà láti dúró, ẹnìkan tí o lè fún ní ipá, ètò kan tí o lè dá sílẹ̀, ìbárẹ́ titun tí o lè bẹ̀rẹ̀, àti àwọn ewu tí o nílò láti kojú.

Bíbélì Wà Láàyè
Ọjọ́ Méje
Ní àtètèkọ́ṣe, ni Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ti ń mú ọkàn àti ẹ̀mí àwọn ènìyàn bọ̀sípò—Ọlọ́run ò sì tíì parí iṣẹ́. Nínú Ètò pàtàkì ọlọ́jọ́-méje yìí, ẹ jẹ́ kí a ṣe àjọyọ̀ agbára Ìwé Mímọ́ tó ń yí ìgbé-ayé ẹni padà nípasẹ̀ ṣíṣe àgbéyẹ̀wò àwọn ọ̀nà tí Ọlọ́run ń gbà lo Bíbélì láti yí àkọsílẹ̀-ìtàn padà àti láti mú àyípadà dé bá ìgbésí ayé àwọn ènìyàn káàkiri àgbáyé.