← Àwon ètò
Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Mak 12
Ìhìnrere Marku
16 Awọn ọjọ
Marku jẹ́ ẹlẹ́rìí àwọn iṣẹ́ ìyanu, ẹ̀kọ́, ikú àti àjínde Jesu, ìhìnrere rẹ̀ tó kún fún àwọn ìṣesí tó wáyé ní kíákíá sì ṣàfihàn ipa Jesu lórí àwọn tó wà láyìíká Rẹ̀. Ṣàwárí àṣẹ àti iṣẹ́ ẹ̀mí Jesu, Ọmọ Ọlọrun àti Ẹni-òróró, nípasẹ̀ ètò ẹ̀kọ́-kíkà ẹsẹ̀-Bibeli-kan-lójúmọ́ yìí ti YouVersion ṣàgbékalẹ̀ rẹ̀.