← Àwon ètò
Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú O. Daf 23:2
Ìdánilójú
Ọjọ́ Mẹ́rin
Olórun fé jé kí o mò pé a tí gbà onlà àti pé ìwo yóò lọ sí òrun! Ìdánilójú rè ń dàgbà sí nípasẹ ìbápàdé pẹ̀lú Olórun àti ṣíṣe àsàrò nínú Ọ̀rọ̀ Rẹ̀. Àwọn ẹsẹ̀ tó tẹ̀lé, nígbà tí o bá há wọn sórí, lè ràn ọ́ lọ́wọ́ láti simi ni ìdánilójú nínú Ọlọ́run ní gbogbo ọjọ́ ayé rè. Jé kí ayé rẹ ní ìyípadà nípa híhá Àwọn Ìwé Mímó sórí! Fún ìlànà ekún rẹ́rẹ́ fún híhá Àwọn Ìwé Mímó sórí, lọ si MemLok.com