1
KỌRINTI KINNI 14:33
Yoruba Bible
Nítorí Ọlọrun kì í ṣe Ọlọrun ìdàrúdàpọ̀. Ọlọrun alaafia ni. Gẹ́gẹ́ bí ó ti rí ninu gbogbo ìjọ eniyan Ọlọrun
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí KỌRINTI KINNI 14:33
2
KỌRINTI KINNI 14:1
Ẹ máa lépa ìfẹ́. Ṣugbọn ẹ tún máa tiraka láti ní Ẹ̀mí Mímọ́, pàápàá jùlọ, ẹ̀bùn ìsọtẹ́lẹ̀.
Ṣàwárí KỌRINTI KINNI 14:1
3
KỌRINTI KINNI 14:3
Ṣugbọn ẹni tí ó ń waasu ń bá eniyan sọ̀rọ̀ fún ìdàgbà ti ẹ̀mí, fún ìtùnú, ati ìwúrí.
Ṣàwárí KỌRINTI KINNI 14:3
4
KỌRINTI KINNI 14:4
Ẹni tí ó ń fi èdè àjèjì sọ̀rọ̀, ara rẹ̀ nìkan ni ó ń mú dàgbà. Ṣugbọn ẹni tí ó ń waasu ń mú ìjọ dàgbà.
Ṣàwárí KỌRINTI KINNI 14:4
5
KỌRINTI KINNI 14:12
Bẹ́ẹ̀ gan-an ni ó rí pẹlu yín. Níwọ̀n ìgbà tí ẹ̀ ń tiraka láti ní ẹ̀bùn Ẹ̀mí Mímọ́, ẹ máa wá àwọn ẹ̀bùn tí yóo mú ìjọ dàgbà.
Ṣàwárí KỌRINTI KINNI 14:12
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò