1
ÀWỌN ỌBA KINNI 16:31
Yoruba Bible
Bí ẹni pé, gbogbo àìdára tí Ahabu ọba ṣe bíi ti Jeroboamu, ọmọ Nebati, kò burú tó, ó tún lọ fẹ́ Jesebẹli ọmọbinrin Etibaali, ọba Sidoni, ó sì ń bọ oriṣa Baali.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ÀWỌN ỌBA KINNI 16:31
2
ÀWỌN ỌBA KINNI 16:30
Ahabu ọmọ Omiri ṣe nǹkan burúkú lójú OLUWA ju gbogbo àwọn tí wọ́n ṣáájú rẹ̀ lọ.
Ṣàwárí ÀWỌN ỌBA KINNI 16:30
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò