Nítorí ó wà ní àkọsílẹ̀ pé,
“Ẹni tí ó bá fẹ́ ìgbé-ayé tí ó wù ú,
tí ó fẹ́ rí ọjọ́ tí ó dára,
ó níláti kó ara rẹ̀ ni ìjánu
pẹlu ọ̀rọ̀ burúkú sísọ,
kí ó má fi ẹnu rẹ̀ sọ̀rọ̀ ẹ̀tàn.
Ó níláti yipada kúrò ninu ìwà burúkú,
kí ó máa hu ìwà rere.
Ó níláti máa wá alaafia,
kí ó sì máa lépa rẹ̀.