1
SAMUẸLI KINNI 10:6
Yoruba Bible
Nígbà náà, ẹ̀mí OLUWA yóo bà lé ọ, o óo sì darapọ̀ mọ́ wọn, o óo sì máa sọ àsọtẹ́lẹ̀, o óo sì yàtọ̀ patapata sí bí o ti wà tẹ́lẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí SAMUẸLI KINNI 10:6
2
SAMUẸLI KINNI 10:9
Yíyí tí Saulu yipada kúrò lọ́dọ̀ Samuẹli, Ọlọrun sọ ọ́ di ẹ̀dá titun. Gbogbo àwọn àmì tí Samuẹli sọ fún un patapata ni ó sì ṣẹlẹ̀ ní ọjọ́ náà.
Ṣàwárí SAMUẸLI KINNI 10:9
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò