1
SAMUẸLI KINNI 20:42
Yoruba Bible
Lẹ́yìn náà ni Jonatani sọ fún Dafidi pé, “Kí Ọlọrun wà pẹlu rẹ. Kí OLUWA ran àwa mejeeji lọ́wọ́ ati àwọn ọmọ wa, kí á lè pa majẹmu tí ó wà láàrin wa mọ́ laelae.” Lẹ́yìn tí Dafidi lọ, Jonatani pada sí ààrin ìlú.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí SAMUẸLI KINNI 20:42
2
SAMUẸLI KINNI 20:17
Jonatani tún mú kí Dafidi ṣe ìbúra lẹ́ẹ̀kan sí i, pẹlu ìfẹ́ tí ó ní sí i. Nítorí pé, Jonatani fẹ́ràn rẹ̀ bí ó ti fẹ́ràn ẹ̀mí ara rẹ̀.
Ṣàwárí SAMUẸLI KINNI 20:17
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò