1
SAMUẸLI KINNI 23:16-17
Yoruba Bible
Jonatani ọmọ Saulu wá a lọ sibẹ ó sì fi ọ̀rọ̀ Ọlọrun gbà á níyànjú. Ó sọ fún un pé, “Má bẹ̀rù, nítorí pé ọwọ́ Saulu, baba mi, kò ní tẹ̀ ọ́. O óo jọba lórí Israẹli, n óo sì jẹ́ igbákejì rẹ.”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí SAMUẸLI KINNI 23:16-17
2
SAMUẸLI KINNI 23:14
Dafidi bá ń lọ gbé orí òkè kan tí ó ṣe é farapamọ́ sí ní aṣálẹ̀ Sifi. Saulu ń wá a lojoojumọ láti pa á, ṣugbọn Ọlọrun kò fi Dafidi lé e lọ́wọ́.
Ṣàwárí SAMUẸLI KINNI 23:14
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò