1
TẸSALONIKA KINNI 3:12
Yoruba Bible
Kí Oluwa mú kí ìfẹ́ yín sí ara yín ati sí gbogbo eniyan kí ó pọ̀ sí i, kí ó sì túbọ̀ jinlẹ̀, gẹ́gẹ́ bí tiwa ti rí si yín.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí TẸSALONIKA KINNI 3:12
2
TẸSALONIKA KINNI 3:13
Kí Oluwa fi agbára fun yín, kí ọkàn yín lè wà ní ipò mímọ́, láìní àléébù, níwájú Ọlọrun Baba wa nígbà tí Oluwa wa Jesu bá farahàn pẹlu gbogbo àwọn ẹni mímọ́ rẹ̀.
Ṣàwárí TẸSALONIKA KINNI 3:13
3
TẸSALONIKA KINNI 3:7
Ará, ìròyìn yìí fún wa ní ìwúrí nípa yín, nítorí igbagbọ yín, a lè gba gbogbo ìṣòro ati inúnibíni tí à ń rí.
Ṣàwárí TẸSALONIKA KINNI 3:7
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò