1
KRONIKA KEJI 26:5
Yoruba Bible
Ó sin Ọlọrun nígbà ayé Sakaraya, nítorí pé Sakaraya ń kọ́ ọ ní ìbẹ̀rù Ọlọrun. Ní gbogbo àkókò tí ó fi ń sin Ọlọrun, Ọlọrun bukun un.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí KRONIKA KEJI 26:5
2
KRONIKA KEJI 26:16
Ṣugbọn nígbà tí Usaya di alágbára tán, ìgbéraga rẹ̀ tì í ṣubú. Ó ṣe aiṣootọ sí OLUWA Ọlọrun rẹ̀. Ó wọ inú tẹmpili OLUWA, ó lọ sun turari lórí pẹpẹ turari.
Ṣàwárí KRONIKA KEJI 26:16
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò