1
SAMUẸLI KEJI 3:1
Yoruba Bible
Àwọn tí wọ́n wà lẹ́yìn ìdílé Saulu, ati àwọn tí wọ́n wà lẹ́yìn ìdílé Dafidi bá ara wọn jagun fún ìgbà pípẹ́. Bí agbára Dafidi ti ń pọ̀ sí i, bẹ́ẹ̀ ni agbára àwọn tí wọ́n wà lẹ́yìn Saulu ń dínkù.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí SAMUẸLI KEJI 3:1
2
SAMUẸLI KEJI 3:18
Àkókò nìyí láti ṣe ohun tí ẹ ti fẹ́ ṣe, nítorí pé OLUWA ti ṣe ìlérí fún Dafidi pé Dafidi ni òun óo lò láti gba àwọn ọmọ Israẹli kúrò lọ́wọ́ àwọn ará Filistia ati gbogbo àwọn ọ̀tá wọn yòókù.”
Ṣàwárí SAMUẸLI KEJI 3:18
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò