1
SAMUẸLI KEJI 5:4
Yoruba Bible
Ẹni ọgbọ̀n ọdún ni, nígbà tí ó gorí oyè, ó sì jọba fún ogoji ọdún.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí SAMUẸLI KEJI 5:4
2
SAMUẸLI KEJI 5:19
Dafidi bi OLUWA pé, “Ṣé kí n kọlu àwọn ará Filistia, ṣé o óo fún mi ní ìṣẹ́gun lórí wọn?” OLUWA dá a lóhùn pé, “Kọlù wọ́n, n óo fún ọ ní ìṣẹ́gun lórí wọn.”
Ṣàwárí SAMUẸLI KEJI 5:19
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò