1
SAMUẸLI KEJI 7:22
Yoruba Bible
OLUWA Ọlọrun, o tóbi gan-an! Kò sí ẹni tí ó dàbí rẹ, bẹ́ẹ̀ ni kò sí Ọlọrun mìíràn lẹ́yìn rẹ, nítorí gbogbo ohun tí a ti fi etí wa gbọ́.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí SAMUẸLI KEJI 7:22
2
SAMUẸLI KEJI 7:13
Òun ni yóo kọ́ ilé fún mi, n óo sì rí i dájú pé ìran rẹ̀ ni yóo máa jọba títí laelae.
Ṣàwárí SAMUẸLI KEJI 7:13
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò