1
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 10:34-35
Yoruba Bible
Peteru bá tẹnu bọ̀rọ̀. Ó ní, “Ó wá yé mi gan-an pé Ọlọrun kì í ṣe ojuṣaaju. Ẹnikẹ́ni tí ó bá bẹ̀rù rẹ̀, tí ó sì ń ṣe rere ni yóo fà mọ́ra láì bèèrè orílẹ̀-èdè tí ó jẹ́.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 10:34-35
2
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 10:43
Òun ni gbogbo àwọn wolii ń jẹ́rìí sí, tí wọ́n sọ pé gbogbo ẹni tí ó bá gbà á gbọ́ yóo ní ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ ní orúkọ rẹ̀.”
Ṣàwárí ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 10:43
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò