1
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 15:11
Yoruba Bible
A gbàgbọ́ pé nípa oore-ọ̀fẹ́ Jesu Oluwa ni a fi gbà wá là, gẹ́gẹ́ bí a ti fi gba àwọn náà là.”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 15:11
2
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 15:8-9
Ọlọrun olùmọ̀ràn ọkàn fún wọn ní ìwé ẹ̀rí nígbà tí ó fún wọn ní Ẹ̀mí Mímọ́ gẹ́gẹ́ bí ó ti fún wa. Kò fi ìyàtọ̀ kankan sáàrin àwa ati àwọn; ó wẹ ọkàn wọn mọ́ nítorí wọ́n gba Jesu gbọ́.
Ṣàwárí ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 15:8-9
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò