1
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 3:19
Yoruba Bible
Nítorí náà, ẹ ronupiwada, kí ẹ yipada sọ́dọ̀ Ọlọrun bí ẹ bá fẹ́ kí á pa ẹ̀ṣẹ̀ yín rẹ́.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 3:19
2
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 3:6
Peteru bá sọ fún un pé, “N kò ní fadaka tabi wúrà, ṣugbọn n óo fún ọ ní ohun tí mo ní. Ní orúkọ Jesu Kristi ti Nasarẹti, máa rìn.”
Ṣàwárí ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 3:6
3
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 3:7-8
Ó bá fà á lọ́wọ́ ọ̀tún, ó gbé e dìde. Lẹsẹkẹsẹ ẹsẹ̀ rẹ̀ ati ọrùn-ẹsẹ̀ rẹ̀ bá mókun. Ó bá fò sókè, ó dúró, ó sì ń rìn. Ó bá tẹ̀lé wọn wọ inú Tẹmpili; ó ń rìn, ó ń fò sókè, ó sì ń yin Ọlọrun.
Ṣàwárí ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 3:7-8
4
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 3:16
Orúkọ Jesu ati igbagbọ ninu orúkọ yìí ni ó mú ọkunrin tí ẹ rí yìí lára dá. Ẹ ṣá mọ̀ ọ́n. Igbagbọ ninu rẹ̀ ni ó fún ọkunrin yìí ní ìlera patapata, gẹ́gẹ́ bí gbogbo yín ti rí i fúnra yín.
Ṣàwárí ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 3:16
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò