1
ẸSITA 1:1
Yoruba Bible
Ní àkókò tí Ahasu-erusi jọba ní ilẹ̀ Pasia, ìjọba rẹ̀ tàn dé agbègbè mẹtadinlaadoje (127), láti India títí dé Kuṣi ní ilẹ̀ Etiopia.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ẸSITA 1:1
2
ẸSITA 1:12
Ṣugbọn nígbà tí àwọn ìwẹ̀fà tí ọba rán jíṣẹ́ fún un, ó kọ̀, kò wá siwaju ọba. Nítorí náà, inú bí ọba gidigidi, inú rẹ̀ sì bẹ̀rẹ̀ sí ru.
Ṣàwárí ẸSITA 1:12
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò