1
ẸKISODU 24:17-18
Yoruba Bible
Lójú àwọn eniyan Israẹli, ìrísí ògo OLUWA lórí òkè náà dàbí iná ńlá tí ń jóni ní àjórun. Mose wọ inú ìkùukùu náà lọ, ó gun orí òkè náà, ó sì wà níbẹ̀ fún ogoji ọjọ́, tọ̀sán-tòru.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ẸKISODU 24:17-18
2
ẸKISODU 24:16
Ògo OLUWA sọ̀kalẹ̀ sórí òkè Sinai, ìkùukùu sì bò ó fún ọjọ́ mẹfa, ní ọjọ́ keje, OLUWA pe Mose láti inú ìkùukùu náà.
Ṣàwárí ẸKISODU 24:16
3
ẸKISODU 24:12
OLUWA wí fún Mose pé, “Gun orí òkè tọ̀ mí wá, kí o dúró sibẹ, n óo sì kó wàláà tí wọ́n fi òkúta ṣe fún ọ, tí mo kọ àwọn òfin ati ìlànà sí, fún ìtọ́ni àwọn eniyan yìí.”
Ṣàwárí ẸKISODU 24:12
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò