1
JẸNẸSISI 46:3
Yoruba Bible
Ọlọrun wí pé, “Èmi ni Ọlọrun baba rẹ, má fòyà rárá láti lọ sí Ijipti, nítorí pé n óo sọ ọ́ di orílẹ̀-èdè ńlá níbẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí JẸNẸSISI 46:3
2
JẸNẸSISI 46:4
N óo bá ọ lọ sí Ijipti, n óo sì tún mú ọ pada wá, ọwọ́ Josẹfu ni o óo sì dákẹ́ sí.”
Ṣàwárí JẸNẸSISI 46:4
3
JẸNẸSISI 46:29
Josẹfu bọ́ sinu kẹ̀kẹ́ ẹlẹ́ṣin rẹ̀, ó lọ pàdé Israẹli, baba rẹ̀ ní Goṣeni. Nígbà tí Josẹfu dé ọ̀dọ̀ baba rẹ̀, ó rọ̀ mọ́ ọn lọ́rùn, ó sì sọkún fún ìgbà pípẹ́.
Ṣàwárí JẸNẸSISI 46:29
4
JẸNẸSISI 46:30
Israẹli bá wí fún Josẹfu, ó ní, “Níwọ̀n ìgbà tí mo ti fi ojú kàn ọ́ báyìí, tí mo sì rí i pé o wà láàyè, bí ikú bá tilẹ̀ wá dé, ó yá mi.”
Ṣàwárí JẸNẸSISI 46:30
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò