1
HEBERU 8:12
Yoruba Bible
Nítorí n óo fi àánú fojú fo ìwà burúkú wọn, n kò sì ní ranti ẹ̀ṣẹ̀ wọn mọ́.”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí HEBERU 8:12
2
HEBERU 8:10
Èyí ni majẹmu tí n óo bá ilé Israẹli dá nígbà tí ó bá yá. N óo fi òfin mi sí inú wọn, n óo kọ ọ́ sí ọkàn wọn, èmi óo jẹ́ Ọlọrun wọn, àwọn náà yóo sì jẹ́ eniyan mi.
Ṣàwárí HEBERU 8:10
3
HEBERU 8:11
Kì yóo sí ìdí tí ẹnìkan yóo fi kọ́ aládùúgbò rẹ̀ tabi arakunrin rẹ̀, pé, ‘Mọ Oluwa.’ Nítorí pé gbogbo wọn ni wọn óo mọ̀ mí, ohun tí ó ṣẹ̀ láti orí àwọn mẹ̀kúnnù inú wọn títí dé orí àwọn eniyan pataki pataki.
Ṣàwárí HEBERU 8:11
4
HEBERU 8:8
Nítorí Ọlọrun rí ẹ̀ṣẹ̀ kà sí wọn lọ́rùn ni ó fi sọ pé, “Oluwa wí pé: Ọjọ́ ń bọ̀ tí èmi yóo bá ilé Israẹli ati ilé Juda dá majẹmu titun.
Ṣàwárí HEBERU 8:8
5
HEBERU 8:1
Kókó ohun tí à ń sọ nìyí, pé a ní irú Olórí Alufaa báyìí, ẹni tí ó jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún ìtẹ́ ọlá ńlá ní ọ̀run.
Ṣàwárí HEBERU 8:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò