1
AISAYA 14:12
Yoruba Bible
“Ọba Babiloni, wò ó! Bí o ti jábọ́ láti ojú ọ̀run, ìwọ tí o dàbí ìràwọ̀ òwúrọ̀! Wò ó bí a ti sọ ọ́ di ẹni ilẹ̀, ìwọ tí o ti pa ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè run rí.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí AISAYA 14:12
2
AISAYA 14:13
Ó pinnu lọ́kàn ara rẹ̀ pé, ‘N óo gòkè dé ọ̀run, n óo gbé ìtẹ́ mi kọjá àwọn ìràwọ̀ ojú ọ̀run; n óo jókòó lórí òkè àpéjọ àwọn eniyan, ní ìhà àríwá ní ọ̀nà jíjìn réré.
Ṣàwárí AISAYA 14:13
3
AISAYA 14:14
N óo gòkè kọjá ìkùukùu ojú ọ̀run, n óo wá dàbí Olodumare.’
Ṣàwárí AISAYA 14:14
4
AISAYA 14:15
Ṣugbọn a já ọ lulẹ̀ sinu isà òkú, sí ìsàlẹ̀ ọ̀gbun.
Ṣàwárí AISAYA 14:15
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò