1
AISAYA 37:16
Yoruba Bible
“Ìwọ OLUWA àwọn ọmọ-ogun, Ọlọrun Israẹli, ìwọ tí ìtẹ́ rẹ wà lórí àwọn Kerubu, ìwọ nìkan ni Ọlọrun gbogbo ìjọba ayé, ìwọ ni ó sì dá ọ̀run ati ayé.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí AISAYA 37:16
2
AISAYA 37:20
Nisinsinyii, OLUWA Ọlọrun wa, gbà wá lọ́wọ́ rẹ̀, kí gbogbo ìjọba ayé lè mọ̀ pé ìwọ nìkan ni OLUWA.”
Ṣàwárí AISAYA 37:20
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò