1
AISAYA 8:13
Yoruba Bible
OLUWA àwọn ọmọ ogun nìkan ni kí o kà sí mímọ́, òun ni kí ẹ̀rù rẹ̀ máa bà ọ́. Òun nìkan ni kí ọ̀rọ̀ rẹ̀ máa pá ọ láyà.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí AISAYA 8:13
2
AISAYA 8:12
“Ìwọ kò gbọdọ̀ lọ́wọ́ sí ọ̀tẹ̀ tí àwọn eniyan yìí ń dì. Bẹ́ẹ̀ ni o kò gbọdọ̀ bẹ̀rù ohun tí wọn ń bẹ̀rù.
Ṣàwárí AISAYA 8:12
3
AISAYA 8:20
Ẹ lọ wádìí ninu ẹ̀kọ́ mímọ́ ati ẹ̀rí. Bí ẹnìkan bá sọ irú ọ̀rọ̀ yìí, kò sí òye ìmọ́lẹ̀ níbẹ̀.
Ṣàwárí AISAYA 8:20
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò