1
JEREMAYA 1:5
Yoruba Bible
“Kí n tó dá ọ sinu ìyá rẹ ni mo ti mọ̀ ọ́, kí wọ́n sì tó bí ọ ni mo ti yà ọ́ sọ́tọ̀, mo yàn ọ́ ní wolii fún àwọn orílẹ̀-èdè.”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí JEREMAYA 1:5
2
JEREMAYA 1:8
Má bẹ̀rù wọn, nítorí mo wà pẹlu rẹ, n óo sì gbà ọ́.”
Ṣàwárí JEREMAYA 1:8
3
JEREMAYA 1:19
Wọn yóo gbógun tì ọ́, ṣugbọn wọn kò ní ṣẹgun rẹ. Nítorí pé mo wà pẹlu rẹ láti gbà ọ́ kalẹ̀. Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”
Ṣàwárí JEREMAYA 1:19
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò