1
JEREMAYA 10:23
Yoruba Bible
OLUWA, mo mọ̀ pé ọ̀nà ẹ̀dá kò sí ní ọwọ́ ara rẹ̀. Kò sí ní ìkáwọ́ ẹni tí ń rìn láti tọ́ ìṣísẹ̀ ara rẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí JEREMAYA 10:23
2
JEREMAYA 10:6
OLUWA, kò sí ẹni tí ó dàbí rẹ, o tóbi lọ́ba, agbára orúkọ rẹ sì pọ̀.
Ṣàwárí JEREMAYA 10:6
3
JEREMAYA 10:10
Ṣugbọn OLUWA ni Ọlọrun tòótọ́, òun ni Ọlọrun alààyè, Ọba ayérayé. Tí inú rẹ̀ bá bẹ̀rẹ̀ síí ru ayé á mì tìtì, àwọn orílẹ̀-èdè kò lè farada ibinu rẹ̀.
Ṣàwárí JEREMAYA 10:10
4
JEREMAYA 10:24
Tọ́ mi sọ́nà, OLUWA, ṣugbọn lọ́nà ẹ̀tọ́ ni kí o bá mi wí, kì í ṣe pẹlu ibinu rẹ, kí o má baà sọ mí di ẹni ilẹ̀.
Ṣàwárí JEREMAYA 10:24
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò