1
JOBU 13:15
Yoruba Bible
Wò ó, yóo pa mí; n kò ní ìrètí; sibẹ n óo wí àwíjàre tèmi níwájú rẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí JOBU 13:15
2
JOBU 13:16
Èyí ni yóo jẹ́ ìgbàlà mi, nítorí pé ẹni tí kò mọ Ọlọrun, kò ní lè dúró níwájú rẹ̀.
Ṣàwárí JOBU 13:16
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò