1
JOBU 28:28
Yoruba Bible
Nígbà náà ni ó sọ fún eniyan pé, ‘Wò ó, ìbẹ̀rù OLUWA ni ọgbọ́n, kí á yẹra fún ibi sì ni ìmọ̀.’ ”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí JOBU 28:28
2
JOBU 28:12-13
Ṣugbọn níbo ni a ti lè rí ọgbọ́n? Níbo sì ni ìmọ̀ wà? “Ẹnikẹ́ni kò mọ ọ̀nà ibi tí ó wà; bẹ́ẹ̀ ni kò sí ní ilẹ̀ alààyè.
Ṣàwárí JOBU 28:12-13
3
JOBU 28:20-21
“Níbo ni ọgbọ́n ti ń wá; níbo sì ni ìmọ̀ wà? Ó pamọ́ lójú gbogbo ẹ̀dá alààyè, ati lójú àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run.
Ṣàwárí JOBU 28:20-21
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò