1
JOBU 34:21
Yoruba Bible
Nítorí pé ojú rẹ̀ tó gbogbo ọ̀nà tí eniyan ń tọ̀, ó sì rí gbogbo ìrìn ẹsẹ̀ wọn.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí JOBU 34:21
2
JOBU 34:32
Kọ́ mi ní ohun tí n kò rí, bí mo bá ti ṣẹ̀ rí, n kò ní ṣe bẹ́ẹ̀ mọ́?’
Ṣàwárí JOBU 34:32
3
JOBU 34:10-11
“Nítorí náà ẹ gbọ́ tèmi, ẹ̀yin olóye, Ọlọrun kì í ṣe ibi, Olodumare kì í ṣe ohun tí kò tọ́. Nítorí a máa san ẹ̀san fún eniyan gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ rẹ̀ ati gẹ́gẹ́ bí ìwà rẹ̀.
Ṣàwárí JOBU 34:10-11
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò