1
JOBU 36:11
Yoruba Bible
Bí wọ́n bá gbọ́ràn, tí wọ́n sì sìn ín, wọn yóo lo ọjọ́ ayé wọn pẹlu ìdẹ̀rùn, wọn yóo ṣe ọ̀pọ̀ ọdún ninu ìgbádùn.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí JOBU 36:11
2
JOBU 36:5
“Ọlọrun lágbára, kì í kẹ́gàn ẹnikẹ́ni, agbára ati òye rẹ̀ pọ̀ gan-an.
Ṣàwárí JOBU 36:5
3
JOBU 36:15
A máa lo ìpọ́njú àwọn tí à ń pọ́n lójú láti gbà wọ́n là, a sì máa lo ìdààmú wọn láti ṣí wọn létí.
Ṣàwárí JOBU 36:15
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò