1
NỌMBA 6:24-26
Yoruba Bible
‘Kí OLUWA bukun yín, kí ó sì pa yín mọ́. Kí OLUWA mú kí ojú rẹ̀ mọ́lẹ̀ sí yín lára, kí ó sì ṣàánú fún yín. Kí OLUWA bojúwò yín, kí ó sì fún yín ní alaafia.’
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí NỌMBA 6:24-26
2
NỌMBA 6:27
“Bẹ́ẹ̀ ni wọn óo fi orúkọ mi súre fún àwọn ọmọ Israẹli, n óo sì bukun wọn.”
Ṣàwárí NỌMBA 6:27
3
NỌMBA 6:23
kí ó sọ fún Aaroni ati àwọn ọmọ rẹ̀ pé, “Báyìí ni ẹ óo máa súre fún àwọn ọmọ Israẹli.
Ṣàwárí NỌMBA 6:23
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò