1
ÌWÉ ÒWE 7:2-3
Yoruba Bible
Pa òfin mi mọ́, kí o lè yè, pa ẹ̀kọ́ mi mọ́ gẹ́gẹ́ bí ẹyin ojú rẹ, wé wọn mọ́ ìka rẹ, kí o sì kọ wọ́n sí oókan àyà rẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 7:2-3
2
ÌWÉ ÒWE 7:1
Ọmọ mi, pa ọ̀rọ̀ mi mọ́, kí o sì fi òfin mi sinu ọkàn rẹ.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 7:1
3
ÌWÉ ÒWE 7:5
kí wọ́n baà lè pa ọ́ mọ́, kúrò lọ́dọ̀ alágbèrè obinrin, ati kúrò lọ́wọ́ onírìnkurìn pẹlu ọ̀rọ̀ dídùn rẹ̀.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 7:5
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò