1
ORIN DAFIDI 121:1-2
Yoruba Bible
Mo gbójú sókè wo àwọn òkè, níbo ni ìrànlọ́wọ́ mi ti ń wá? Ìrànlọ́wọ́ mi ń ti ọ̀dọ̀ OLUWA wá, ẹni tí ó dá ọ̀run ati ayé.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 121:1-2
2
ORIN DAFIDI 121:7-8
OLUWA óo dáàbò bò ọ́ lọ́wọ́ gbogbo ibi, yóo pa ọ́ mọ́. OLUWA yóo pa àlọ ati ààbọ̀ rẹ mọ́, láti ìsinsìnyìí lọ ati títí lae.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 121:7-8
3
ORIN DAFIDI 121:3
Kò ní jẹ́ kí ẹsẹ̀ rẹ ó yẹ̀, ẹni tí ń pa ọ́ mọ́ kò ní tòògbé.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 121:3
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò