1
ORIN DAFIDI 135:6
Yoruba Bible
Bí ó ti wu OLUWA ni ó ń ṣe lọ́run ati láyé, ninu òkun ati ninu ibú.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 135:6
2
ORIN DAFIDI 135:3
Ẹ yin OLUWA, nítorí pé ó ṣeun; ẹ kọrin ìyìn sí i, nítorí pé olóore ọ̀fẹ́ ni.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 135:3
3
ORIN DAFIDI 135:13
OLUWA, orúkọ rẹ yóo wà títí lae, òkìkí rẹ óo sì máa kàn títí ayé.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 135:13
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò