1
ORIN DAFIDI 137:1
Yoruba Bible
Lẹ́bàá odò Babiloni ni a jókòó, tí a sọkún, nígbà tí a ranti Sioni.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 137:1
2
ORIN DAFIDI 137:3-4
nítorí pé níbẹ̀ ni àwọn tí ó kó wa ní ìgbèkùn ti ní kí á kọrin fún àwọn. Àwọn tí ó ń pọ́n wa lójú sọ pé kí á dá àwọn lárayá, wọ́n ní, “Ẹ kọ orin Sioni kan fún wa.” Báwo ni a óo ṣe kọ orin OLUWA ní ilẹ̀ àjèjì?
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 137:3-4
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò