1
ORIN DAFIDI 148:13
Yoruba Bible
Ẹ jẹ́ kí wọn yin orúkọ OLUWA, nítorí pé orúkọ rẹ̀ nìkan ni ó ga jù; ògo rẹ̀ sì ga ju ayé ati ọ̀run lọ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 148:13
2
ORIN DAFIDI 148:5
Ẹ jẹ́ kí wọ́n máa yin orúkọ OLUWA, nítorí nípa àṣẹ rẹ̀ ni a fi dá wọn.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 148:5
3
ORIN DAFIDI 148:1
Ẹ yin OLUWA! Ẹ yin OLUWA, ẹ̀yin ẹ̀dá ọ̀run, ẹ yìn ín lókè ọ̀run.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 148:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò