1
ORIN DAFIDI 19:14
Yoruba Bible
Jẹ́ kí ọ̀rọ̀ ẹnu mi, ati àṣàrò ọkàn mi jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà ní ojú rẹ, OLUWA ibi ààbò mi ati olùràpadà mi.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 19:14
2
ORIN DAFIDI 19:7
Òfin OLUWA pé, a máa sọ ọkàn jí; àṣẹ OLUWA dájú, ó ń sọ òpè di ọlọ́gbọ́n.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 19:7
3
ORIN DAFIDI 19:1
Ojú ọ̀run ń sọ̀rọ̀ ògo Ọlọrun, òfuurufú sì ń kéde iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 19:1
4
ORIN DAFIDI 19:8
Ìlànà OLUWA tọ́, ó ń mú ọkàn yọ̀, àṣẹ OLUWA péye, a máa lani lójú.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 19:8
5
ORIN DAFIDI 19:9
Ìbẹ̀rù OLUWA pé, ó wà títí lae, ìdájọ́ OLUWA tọ́, òdodo ni gbogbo wọn.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 19:9
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò