1
ORIN DAFIDI 69:30
Yoruba Bible
Èmi ó fi orin yin orúkọ Ọlọrun; n óo fi ọpẹ́ gbé e ga.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 69:30
2
ORIN DAFIDI 69:13
Ṣugbọn ní tèmi, OLUWA, ìwọ ni mò ń gbadura sí ní àkókò tí ó bá yẹ, Ọlọrun, ninu ọ̀pọ̀ ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀, ninu agbára ìgbàlà rẹ, Ọlọrun dá mi lóhùn.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 69:13
3
ORIN DAFIDI 69:16
Dá mi lóhùn, OLUWA, nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ dára; fojú rere wò mí, gẹ́gẹ́ bí ọpọlọpọ àánú rẹ.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 69:16
4
ORIN DAFIDI 69:33
Nítorí OLUWA a máa gbọ́ ti àwọn aláìní, kì í sìí kẹ́gàn àwọn eniyan rẹ̀ tí ó wà ní ìgbèkùn.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 69:33
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò