1
ORIN DAFIDI 72:18
Yoruba Bible
Ẹni-ìyìn ni OLUWA Ọlọrun Israẹli, ẹni tí ó ń ṣe iṣẹ́ ìyanu tí ẹlòmíràn kò lè ṣe.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 72:18
2
ORIN DAFIDI 72:19
Ẹni ìyìn títí lae ni ẹni tí orúkọ rẹ̀ lókìkí, kí òkìkí rẹ̀ gba ayé kan! Amin! Amin.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 72:19
3
ORIN DAFIDI 72:12
Nítorí pé a máa gba talaka tí ó bá ké pè é sílẹ̀; a sì máa gba àwọn tí ìyà ń jẹ sílẹ̀, ati àwọn tí kò ní olùrànlọ́wọ́.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 72:12
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò