1
ORIN DAFIDI 83:18
Yoruba Bible
Jẹ́ kí wọn mọ̀ pé ìwọ nìkan, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ OLUWA, ni Ọ̀gá Ògo lórí gbogbo ayé.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 83:18
2
ORIN DAFIDI 83:1
Ọlọrun, má dákẹ́; má wòran; Ọlọrun má dúró jẹ́ẹ́!
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 83:1
3
ORIN DAFIDI 83:16
Da ìtìjú bò wọ́n, kí wọn lè máa wá ọ kiri, OLUWA.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 83:16
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò