1
ORIN DAFIDI 85:2
Yoruba Bible
O dárí àìdára àwọn eniyan rẹ jì wọ́n; o sì bo gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ wọn mọ́lẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 85:2
2
ORIN DAFIDI 85:10
Ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ ati òtítọ́ yóo pàdé; òdodo ati alaafia yóo dì mọ́ ara wọn.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 85:10
3
ORIN DAFIDI 85:9
Nítòótọ́, ìgbàlà rẹ̀ wà nítòsí fún àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀; kí ògo rẹ̀ lè wà ní ilẹ̀ wa.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 85:9
4
ORIN DAFIDI 85:13
Òdodo yóo máa rìn lọ níwájú rẹ̀, yóo sì sọ ipasẹ̀ rẹ̀ di ọ̀nà.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 85:13
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò