1
ÌFIHÀN 18:4
Yoruba Bible
Mo tún gbọ́ ohùn mìíràn láti ọ̀run tí ó sọ pé, “Ẹ jáde kúrò ninu rẹ̀, ẹ̀yin eniyan mi, kí ẹ má baà ní ìpín ninu ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, kí ẹ má baà fara gbá ninu ìjìyà rẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ÌFIHÀN 18:4
2
ÌFIHÀN 18:2
Ó wá kígbe pé, “Ó tú! Babiloni ìlú ńlá tú! Ó wá di ibi tí àwọn àǹjọ̀nnú ń gbé, tí ẹ̀mí Èṣù oríṣìíríṣìí ń pààrà, tí oríṣìíríṣìí ẹyẹkẹ́yẹ ń kiri.
Ṣàwárí ÌFIHÀN 18:2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò