1
I. Kor 1:27
Bibeli Mimọ
Ṣugbọn Ọlọrun ti yàn awọn ohun wère aiye lati fi dãmu awọn ọlọgbọ́n; Ọlọrun si ti yàn awọn ohun ailera aiye lati fi dãmu awọn ohun ti o li agbara
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí I. Kor 1:27
2
I. Kor 1:18
Nitoripe wère li ọ̀rọ agbelebu si awọn ti o nṣegbé; ṣugbọn si awa ti a ngbalà, agbara Ọlọrun ni.
Ṣàwárí I. Kor 1:18
3
I. Kor 1:25
Nitoripe wère Ọlọrun gbọ́n jù enia lọ; ati ailera Ọlọrun li agbara jù enia lọ.
Ṣàwárí I. Kor 1:25
4
I. Kor 1:9
Olododo li Ọlọrun, nipasẹ ẹniti a pè nyin sinu ìdapọ Ọmọ rẹ̀ Jesu Kristi Oluwa wa.
Ṣàwárí I. Kor 1:9
5
I. Kor 1:10
Mo si bẹ̀ nyin, ará, li orukọ Oluwa wa Jesu Kristi, ki gbogbo nyin mã sọ̀rọ ohun kanna, ati ki ìyapa ki o máṣe si ninu nyin; ṣugbọn ki a le ṣe nyin pé ni inu kanna, ati ni ìmọ kanna.
Ṣàwárí I. Kor 1:10
6
I. Kor 1:20
Ọlọ́gbọn na ha da? akọwe na ha da? ojiyan aiye yi na ha da? Ọlọrun kò ha ti sọ ọgbọ́n aiye yi di wère?
Ṣàwárí I. Kor 1:20
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò