1
I. Kor 7:5
Bibeli Mimọ
Ẹ máṣe fà sẹhin kuro lọdọ ara nyin, bikoṣe nipa ifimọṣọkan, ki ẹnyin ki o le fi ara nyin fun àwẹ ati adura; ki ẹnyin ki o si tún jùmọ pade, ki Satani ki o máṣe dán nyin wò nitori aimaraduro nyin.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí I. Kor 7:5
2
I. Kor 7:3-4
Ki ọkọ ki o mã ṣe ohun ti o yẹ si aya: bẹ̃ gẹgẹ si li aya pẹlu si ọkọ. Aya kò li agbara lori ara rẹ̀, bikoṣe ọkọ: bẹ̃ gẹgẹ li ọkọ pẹlu kò si li agbara lori ara rẹ̀, bikoṣe aya.
Ṣàwárí I. Kor 7:3-4
3
I. Kor 7:23
A ti rà nyin ni iye kan; ẹ máṣe di ẹrú enia.
Ṣàwárí I. Kor 7:23
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò