1
I. A. Ọba 14:8
Bibeli Mimọ
Ti mo si fà ijọba ya kuro ni ile Dafidi, mo si fi i fun ọ: sibẹ iwọ kò ri bi Dafidi iranṣẹ mi, ẹniti o pa ofin mi mọ, ti o si tọ̀ mi lẹhin tọkàntọkàn rẹ̀, lati ṣe kiki eyi ti o tọ li oju mi
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí I. A. Ọba 14:8
2
I. A. Ọba 14:9
Ṣugbọn iwọ ti ṣe buburu jù gbogbo awọn ti o ti wà ṣaju rẹ: nitori iwọ ti lọ, iwọ si ti ṣe awọn ọlọrun miran, ati ere didà, lati ru ibinu mi, ti iwọ si ti gbé mi sọ si ẹhin rẹ
Ṣàwárí I. A. Ọba 14:9
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò