1
I. A. Ọba 16:31
Bibeli Mimọ
O si ṣe, bi ẹnipe o ṣe ohun kekere fun u lati ma rìn ninu ẹ̀ṣẹ Jeroboamu, ọmọ Nebati, o si mu Jesebeli, ọmọbinrin Etbaali, ọba awọn ara Sidoni li aya, o si lọ, o si sin Baali, o si bọ ọ
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí I. A. Ọba 16:31
2
I. A. Ọba 16:30
Ahabu, ọmọ Omri, si ṣe buburu li oju Oluwa jù gbogbo awọn ti o wà ṣaju rẹ̀ lọ.
Ṣàwárí I. A. Ọba 16:30
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò