1
I. A. Ọba 4:29
Bibeli Mimọ
YBCV
Ọlọrun si fun Solomoni li ọgbọ́n ati oye li ọ̀pọlọpọ, ati oye gbigboro, gẹgẹ bi iyanrin ti o wà leti okun.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí I. A. Ọba 4:29
2
I. A. Ọba 4:34
Ẹni pupọ si wá lati gbogbo orilẹ-ède lati gbọ́ ọgbọ́n Solomoni; ani lati ọdọ gbogbo awọn ọba aiye, ti o gburo ọgbọ́n rẹ̀.
Ṣàwárí I. A. Ọba 4:34