1
I. Tes 3:12
Bibeli Mimọ
Ki Oluwa si mã mu nyin bisi i, ki ẹ si mã pọ̀ ninu ifẹ si ọmọnikeji nyin, ati si gbogbo enia, gẹgẹ bi awa ti nṣe si nyin
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí I. Tes 3:12
2
I. Tes 3:13
Ki o ba le fi ọkàn nyin balẹ li ailabukù ninu ìwa mimọ́ niwaju Ọlọrun ati Baba wa, nigba atiwá Jesu Kristi Oluwa wa pẹlu gbogbo awọn enia mimọ́ rẹ̀.
Ṣàwárí I. Tes 3:13
3
I. Tes 3:7
Nitori eyi, ará, awa ni itunu lori nyin ninu gbogbo wahalà ati ipọnju wa nitori igbagbọ́ nyin
Ṣàwárí I. Tes 3:7
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò